OJU IMO TECH

OJU IMO TECH Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from OJU IMO TECH, Ayetoro-Itele, .
(1)

E k'aabo si OJU_IMO TECH

A kọ́ ọ bí o ṣe lè lo AI láti ṣiṣẹ́ ọlọ́gbọn, kó owo, àti láti dàgbà ní ayé oni-nọ́mbà.

🎓 AI Tutorials
💼 Make Money with AI
📱 Tools & Tips (ní èdè Yorùbá)

14/05/2026
14/05/2026

Ẹ ma sùn lórí eye2.ai o! 👀🔥

This AI tool different gan-an!
Mo test e, honestly… ọpọlọ mi kun

eye2.ai fit help you create contents, work faster, think smarter, àti reduce stress for your daily online work.
Content creators, business owners, students, everybody need to check this out!

Àwọn tó mọ tech trends tẹlẹ ti bẹrẹ sí í nlo

Ṣé ìwọ náà fẹ́ level up digitally?

eye2.ai no be normal tool o… this one loud! 🔥

With Olalekan Adeeko – I just got recognised as one of their top fans! 🎉
14/05/2026

With Olalekan Adeeko – I just got recognised as one of their top fans! 🎉

On OJU IMO TECH, we dey explore how AI dey change the way we work and create 💡Whether na creativity or logic you need, C...
11/05/2026

On OJU IMO TECH, we dey explore how AI dey change the way we work and create 💡

Whether na creativity or logic you need, ChatGPT and Gemini AI dey help bring ideas to life in different ways.

So tell us truthfully 👇
Which one you dey prefer for your daily work or projects?
And for image generation, who you trust pass

ChatGPT or Gemini?

Ẹ jẹ́ ká mọ̀ ìrírí yín nínú comments 👇

11/05/2026



゚viralシfypシ゚

🤖 AI ti dé o! ẹni tí kò bá kọ́ ọ́ báyìí, ó lè ṣòro láti bá ayé tuntun mu lọ́la.At Ojú-Imo TECH, a ń kọ́ ọ bí o ṣe lè lo ...
11/05/2026

🤖 AI ti dé o! ẹni tí kò bá kọ́ ọ́ báyìí, ó lè ṣòro láti bá ayé tuntun mu lọ́la.

At Ojú-Imo TECH, a ń kọ́ ọ bí o ṣe lè lo Artificial Intelligence (AI) fún:
✅ Content Creation
✅ Business Growth
✅ Online Work
✅ Productivity
✅ Digital Skills

Ìmọ̀ ẹrọ ò gbọdọ̀ jẹ́ fún àwọn oyinbo nìkan. Àwa náà lè kọ́ ẹ, ká sì fi ṣe owó 💻🔥

Má jẹ́ kí “mi ò mọ̀” dá ọ lẹ́yìn.
Join our AI training today and upgrade yourself!

📩 Send us a DM now 08082660809
Ojú-Imo TECH — “Imọ̀ ọjọ́ iwájú fún gbogbo ènìyàn.”

11/05/2026

E ku ìbẹ̀rẹ̀ òsè tuntun.
Ki Olórun fún wa ni alààfíà, ayò, owó, oríre àti àṣeyọri ni gbogbo ipà wa.
Ki àǹfààni tuntun, àlàánú ati ìbàdí pọ̀ si ni ọ̀sẹ̀ yìí.
Happy New Week!

04/05/2026

“Ojú-Imọ Tech is Back! 🔥 Kọ AI ní Yorùbá”

Ẹ kaabo sí ọ̀sẹ̀ tuntun!

Welcome to a brand new week on Ojú-Imọ OJU IMO TECH ibi tá a ti ń kọ́ tech ní èdè Yorùbá, kí ìmọ̀ lè ye gbogbo wa dáadáa.

This week, class wa máa bẹ̀rẹ̀ padà no dulling! A ó tún kọ́ àwọn tech skills tó ṣe pàtàkì, ní simple, clear Yoruba + English mix, kí o lè understand and apply am easily.

👉 Ṣé o fẹ́ learn tech without confusion?
👉 Ṣé o fẹ́ upgrade ara rẹ̀ and make more money with digital skills?

Má ṣe miss out!

📌 Follow page yìí now
📌 Turn on notifications
📌 Share with your friends tí wọ́n fẹ́ kọ́ tech

💬 Drop “I’M READY” ní comment, kí a lè carry you along from Day 1!

Majonagbe Fausat Omobolaji


゚viralシfypシ゚

Ìṣe amurele àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wá lẹhin Training ọfẹ́ olojo meta👏👏👏👏👏👏👏👏👏👏
20/04/2026

Ìṣe amurele àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wá lẹhin Training ọfẹ́ olojo meta
👏👏👏👏👏👏👏👏👏👏

🎓 OJÚ-ÌMỌ̀ TECH“AI in Yorùbá: From Beginner to Income Earner”Ẹ darapọ̀ mọ́ kiláàsì WhatsApp wa⬇️
20/04/2026

🎓 OJÚ-ÌMỌ̀ TECH

“AI in Yorùbá: From Beginner to Income Earner”

Ẹ darapọ̀ mọ́ kiláàsì WhatsApp wa⬇️

Kí Ọlọ́run ṣí ilẹ̀kùn oore-ọ̀fé sí ọ, kí Ó dáàbò bo ọ àti àwọn olólùfẹ́ rẹ, kí Ó sì fún ọ ní agbára fún ọ̀sẹ̀ tuntun tó ...
19/04/2026

Kí Ọlọ́run ṣí ilẹ̀kùn oore-ọ̀fé sí ọ, kí Ó dáàbò bo ọ àti àwọn olólùfẹ́ rẹ, kí Ó sì fún ọ ní agbára fún ọ̀sẹ̀ tuntun tó ń bọ.

kí gbogbo àdúrà ìkọ̀kọ̀ rẹ gba ìdáhùn, kí gbogbo ìfẹ́ rere inú ọkàn rẹ sì ṣẹ.


Address

Ayetoro-Itele

112101

Telephone

+2348140110054

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OJU IMO TECH posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

  • Want your practice to be the top-listed Law Practice?

Share